كوراني الابونلي إي يوروبا
Itunmo awon oro Kurani Alaponle ti o se gba ra lee ni ede Yoruba pelu ki kaa ati ti tuu pelu ohun.
O le gbaa ohun elo yi ka le، o si tun le maa woo oju ewe Kurani Alaponle ni Ede (Yoruba) pelu onaa ti o rorun ju lo، ati pelu onaa ti o se oju loin ti o si daa ra، e yi awon akose -monse nkan yiya ati i se kurani lo so ni agabye se fi ko.
E yi je ise agbese ti o je oofee ti ko si ni ipolongo ninu، ti o wa fun gbobgbo fun la ti maa loo، ni ti to ri Olohun.
*** Awon nkan esa ohun elo ***
- O rorun la ti lo: O si tun ni fonti ti o mon ni won ba ti o si ni orisis agbara ti on te si waju.
- Iwadi yara-yara ninu awon oro Kurani Alaponle ati ninu awon oruko ogba oro ati eka-eka Kurani.
- Ki ka Kurani: Je igbadun ki ka Kurani Alaponle ti a da ko lati ibi ti o se gbaa ra le ati e yi ti a se lo so lo so lo na ti o daa raa.
- Awon itumon Kurani Alaponle: Gbo Kurani Alaponle ni ede re peu bi awon itumon re se ti wa ni ede Yoruba.
- Awon Ede orisisi: Maa lo ohun elo yi pelu ede re ta bi ede miran ti o ni fe si laa ti maa wo Kurani.
- Ki ka Kurani: Maa gbo ki ka Kurani Alaponle pelu ohun awon oluka Kurani إلى gba ju mo ati awon ti won man kaa Kurani pelu ohun dun-dun.
- Ti tumon Kurani pelu ohun: Gbigbo itumon Kurani Alaponle pelu ohun ni ede Yoruba.
- Ti tan ohun ti o loo si waju: Ti tan ohun yi o fun ni awon anfani agbara ti o lo si waju gege bi pi pi paara e yi ti yi o ron oo lo wo laa ti ha Kurani Alaponle.
- lā: Fi awon āmi ibi a ti ri awon anfani ati sise idari won، ki o le rọrun la ti dari si awon aye lati duro ni awon amin (Āyah) ko kon.
- Nkan ti a yan laa yo: Fi awon orisis amin (Āyah) ti a yan laa yo si be، ki o la sa re pa da si be ti o ba ya.
- Fi fi irori ye si be: Fi irori ati ironu si be laa rin ki ka Al-Kurani tabi ni igba ti a ban ka itumo re.
- pin nkan pelu elomiran: Pin awon ami (Āyah) tabi awon itumon re pelu awon ọrẹ rẹ lati ibi awon ohun a tẹle ati awon ona ayelujara.
- Mi mo nkan ni o na aara: Sise a sa yan awon aawọ orisisi ati awon nkan yoro-yoro ti o se oju loin، ati mi mo nkan ni ti igba lode ti a mu ni ibi olaju awon elede Yoruba.
Kurani Alaponle - Yoruba Quran
Itunmo awon oro Kurani Alaponle ti o se gba ra lee ni ede Yoruba pelu ki kaa
معلومات عن Kurani Alaponle - Yoruba Quran
اسم الحزمة | online.smartech.quran.yoruba | |
الترخيص | Free | |
نظام التشغيل | Android | |
الفئة | EDUCATION | |
اللغة |
English + 15
|
|
المؤلف | Quran Audio Library | |
التحميلات | 10000 | |
التاريخ | Apr 15, 2023 | |
إعلان | غير محدد |
توفر Valores Banistmo الوصول عبر الإنترنت إلى حساباتك الاستثمارية على مدار الساعة طوال أيام الأسبوع.
توفر Valores Banistmo الوصول عبر الإنترنت إلى حساباتك الاستثمارية على مدار الساعة طوال أيام الأسبوع.